Mo sun lo, n ko mo igba ti eronpileeni si

Anuncio
E ba wa dele
E mo nipa wa
ba wa sise Adiresi wa
E polowo oja yin
AKEDE Agbaye
Idanileko ALAROYE
Mo sun lo, n ko mo igba ti eronpileeni si
Bi o ba fe
Awon Iroyin to se koko
A
Meji ninu awon
n’Ikeôja yeôn. Oun lo kuku n pariwo bi mo sôe feôeô woôle. Woôn ti gba baagi loôwoô mi, woôn ti ni ki
n boô bata, woôn ni sôe ko tun si kinni kan lara mi, mo ni ko si nnkan kan lara mi, sôugboôn bi mo
ba ti feôeô koôja, beôeô ni kinni naa yoo figbe boônu, ti yoo sôaa maa pariwo sôaa. O to eôeômeôrin ti
mo n loô ti mo n boô beôeô, nigba to si su mi ni mo ni n o loô moô. Igba naa ni woôn sôeôsôeô waa mu
mi woônu yara kekere kan, n lobinrin kan ba teôle mi, lo n soô pe mama eô ma binu.
Mo ti binu, mo ni ki lo n sôe yin bayii, sôe nigba ti masôinni yin ko waa daa yii, sôe emi ni eô o
maa waa fiya jeô, abi eô ri eôru kankan loôwoô mi ni. Igba to mu mi woô yara yii lo ni ki n sôaa roôra
boô asôoô mi ki awoôn le wo o pe ko si nnkan ti ko dara lara mi, o tun ni ki n tun ma binu, isôeô
ofin loun n sôe, isôeô ti ijoôba ni kawoôn sôe niyeôn. Lemi ba n wo o, n ko si wi nnkan kan moô. Abi,
oômoô oôloômoô, kin ni mo feôeô tun maa wi fun un, nigba to jeô isôeô tawoôn oôga reô ni ko maa sôe lo n
sôe, ko ma waa jeô pe emi ni n oo fi temi koba a.
Nibi ti a ti n soôroô leôni keji reô ti woôle, ni woôn ba di meji lori emi nikan. Obinrin Ibo kan
bayii lo sôikeji eô, iyeôn bajeô bii oôwoô osi bayii. Sôugboôn ko bu mi o. Nigba ti ki i sôe pe woôn sôepe
fun un, mo n gboô gbogbo eebo to n soô, bo tileô jeô pe n ko le soô oô, mo si moô pe o n beere loôwoô
oômoô tibi yeôn pe sôe woôn ti ri eôru ti mama gbe lara eô, niyeôn ba moô oôn loju. Igba ti mo tu iro
asôoô leesi ti mo woô ti mo fi seôgbeôeô kan loômoô yeôn ri sikeôeôti mi. Sikeôeôti alasôoô ni, tobi ni, ki i sôe
sikeôeôti lasan, o si ni ibi kan ti a ti sôe siipu si i.
Latigba ti mo ti n taja ni kekere lo ti jeô iru sikeôeôti ti mo maa n woô niyeôn, nitori owo mi si ni,
n ko feô ki owo mi soônu. Igba ti mo waa dagba naa tan, sikeôeôti ti mo maa n woô naa niyeôn,
nibeô ni mo si maa n fi koôkoôroô koôboôoôdu mi si, nitori ko too di pe mo n kowo si banki,
koôboôoôdu mi ni gbogbo ohun ti mo ni maa n wa, ko si seônikan to le soô pe oun ri koôkoôroô reô
nileô ri. Sôe loju Alaaji ni n oo tileô ti fi koôkoôroô koôboôoôdu sileô, nijoô ti kinni eô ba woôle si i lara, to
feôeô nawo ti ko ri i na, bo ba foju kan koôkoôroô koôboôoôdu mi, ibeô ni yoo loô.
Asôe gbogbo bi mo sôe n loô ti mo n boô ti kinni yeôn n pariwo yeôn, nitori koôkoôroô koôboôoôdu mi to
wa ninu sikeôeôti mi ni. Awoôn koôkoôroô naa kuku tieô ti poô, meôrin ni mo so poô moô ara woôn, nitori
koôkoôroô duroôoô mi ni sôoôoôbu naa wa nibeô, awoôn koôkoôroô naa si tobi dieô bayii. Asôe awoôn koôkoôroô
yii lo n pariwo lara mi. Bi oômoôbinrin to jeô Yoruba yeôn ti ri i pe sikeôeôti ti mo woô ni siipu, lo
ba ni, “Mama, sôe ki i sôe pe nnkan kan wa ninu sikeôeôti yeôn, nibi ti siipu wa yeôn@” Ni mo ba ni
koôkoôroô koôboôoôdu mi nikan lo wa nibeô, abi eewoô ni ki n mu un dani ni.
Nisôe ni awoôn mejeeji gbeôrin-in, ni oômoô yeôn ba ni ki n yoô koôkoôroô jade, ni mo ba yoô oô. Ni woôn
ba tun n reôrin-in, lo ba ni, “Mama, eô ro asôoô yin, o ya ka loô.” Ni mo ba n wo woôn, nigba ti a
de ita ni woôn ba tun ni ki n koôja labeô masôinni woôn yeôn, sôugboôn woôn ti mu koôkoôroô mi dani, bi
mo sôe koôja bayii, geerege ni mo loô, ko sariwo kankan moô. Mo ni, “Oniranu ma lawoôn
oyinbo yii o, sôe nitori koôkoôroô lasan, sôe nitori koôkoôroô mi lariwo sôe to bayii, awoôn ara Osôodi o
gboôdoô gboô.” Bi mo sôe jade ni woôn ko gbogbo eôru mi le mi loôwoô, ni woôn ba juwe oôna fun mi.
Emi tieô ti ro pe eôronpileeni ti n loô ni, ni mo ba beôreô si i rin loô faufau, ti mo n fi iwe oôwoô mi
han woôn, ko waa too di pe oômoô kan ni ibeô loun naa n loô, la ba joô rin debeô. Asôe eôronpileeni
ko ti i sôetan. A koôkoô jokoo bii nnkan siwaju ibi kan ti woôn sôe bii geeti kekere si bayii, awoôn
osôisôeô eôronpileeni yeôn ni woôn wa nibeô, emi o moô nnkan ti woôn sôe. O ma to wakati kan ti mo
ma lo lori ijokoo nibeô, igba to si ya lawoôn ti mo ni woôn wa leônu geeti yeôn beôreô si i fi imu
soôroô.
Oyinbo ti woôn n soô yatoô gan-an si eyi ti mo ti gboô teôleô, oômoôbinrin ti a sôaa joô rin debeô yeôn lo
tun waa ba mi pe o ti ya, awa ni woôn n pe yeôn. Emi o feôran oômoô naa, o ti bora, gbogbo ara eô
ti di funfun, iru awoôn oômoô ti n ki i feô ki woôn sunmoô mi bo ba jeô aaye mi ni mo wa l’Osôodi
ni. Sôugboôn kin ni n oo waa sôe niru ibi yii bayii, kin ni mo feôeô sôe. Nigba to tieô jeô oun lo n fi
foomu lodo Ali Modu
woôn oyinbo yeôn, oniwahala ni woôn. OÙloôrun lo moô iru masôinni ti woôn gbe si eôeôpoôoôtu
komisanna Mimiko gba
Sheriff
Nitori Adebayo, egbe
PDP ati APC soko oro
sira won l'Ekiti
Wolii fun omo bibi inu
e loyun l'Ondo, lo ba ni
ise esu ni
Kanselo fee gba gomina
lalejo, lo ba loo raso
awin
Muyideen fi naira
mewaa tan omo odun
meta, lo ba ba a lo po
l'Ekoo
Josiah lu iyawo re pa
l'Erio-Ekiti, o lo fi
ibalopo du oun
E tun pade wa lori ero
E wa awon iroyin wa
mi moôna, to n sôe mi bii iya reô, sôe ki n waa maa kanra moô oôn ni. Mo ti gba kamu temi f’OÙloôrun. Mo feô mo koô,
afi ki n feôran oômoô naa.
Igba ti woôn ti gba iwe oôwoô mi ni oômoô yeôn ti ni ki n teôle oun, mo si teôle e titi ti a fi de eônu eôronpileeni bayii,
nibeô ni mo ti ri oômoôbinrin oyinbo kan ati oômoô tiwa kan, oôoôkan ti mo tun wo bayii, mo tun ri awoôn oyinbo
meji, awoôn naa n loô ni. Mo ni o tieô ti daa, emi o moô pe awoôn oyinbo poô beôeô yeôn ni Naijiria wa. OÙmoô ti
OÙloôrun ran si mi yeôn ko sôaa fi mi sileô, oun lo loôoô fi ibi ijokoo mi han mi, o ni nibi ti n oo jokoo si niyeôn. Mo
koôkoô ro pe ibeô ko le gba mi ni, nitori ijokoo naa ha dieô loju mi, sôugboôn nigba ti mo woôle ti mo jokoo, o gba
mi daadaa.
OÙmoô naa lo fi beôliiti kan han mi, lo ba koô mi bi mo sôe ma de e moôra mi, o ni ni gbogbo igba ni mo gboôdoô de
e o. Oun lo ba mi sôi kinni teôlifisôan to wa niwaju mi, o ni bi mo ba feôeô maa wo teôlifisôan. Mo ni mo feôeô wo o,
mo soô fun un pe ibi tawoôn Bello ati Aluweô ti maa n sôere ni mo feô, tabi Baba Suwe, nisôe lo fi mi reôrin-in, lo ni
awoôn oyinbo nikan ni mo le ri nibi o. Mo ni ki lo kan mi kan awoôn oyinbo, emi ki i wo ere oyinbo o, mo ni
ko tete ba mi pa a. Lo ba ba mi pa a ko too loôoô maa wa ijokoo tireô kiri.
Boya wahala ti mo ti sôe lati aaroô ni o, n ko tileô moô, ohun ti mo kan moô ni pe, ko peô ti oômoô yeôn kuro loôdoô mi
ti mo fi sun loô, mo sun loô bii eôni to wa nile ni o, n ko si moôgba ti eôronpileeni sôi rara.
Descargar